reluwee
Yoruba

Ọ̀nà rélùwéè ní Yába, ìlú Èkó
Pronunciation
- IPA(key): /ɾé.lù.wéè/
Noun
rélùwéè
- railway
- railroad
- Synonyms: ọ̀nà ojú irin, ọ̀nà rélùwéè
- train
- Synonyms: ọkọ̀ ojú irin, ọkọ̀ rélùwéè
- N kì í wọ rélùwéè ní òpin ọ̀sẹ̀. ― I don't take the train on weekends.
- railroad
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.