olu-ilu

Yoruba

Alternative forms

  • olúùlú
  • olúìlú
  • وْلُ-اِلُ

Etymology

From olú (main, chief) + ìlú (city)

Pronunciation

  • IPA(key): /ō.lú.ì.lú/

Noun

olú-ìlú

  1. capital city
    Láyé àtijọ́ ni Ìlú-Ọba Ọ̀yọ́, olú-ìlú kín-ìn-ní wọn jẹ́ Ọ̀yọ́-IléIn the days of old is when the Ọ̀yọ́ Empire existed, it's first capital was Ọ̀yọ́-Ilé
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.