ile-ikawe

Yoruba

Ilé-ìkàwé

Alternative forms

Etymology

From ilé (house) + ìkàwé (act of reading books), literally the house of reading books.

Pronunciation

IPA(key): /ī.lé.ì.kà.wé/

Noun

ilé-ìkàwé

  1. library
    Synonym: láíbìrì
    Mo ń lọ sí ilé-ìkàwé láti yá ìwé kíláàsì mi.
    I'm going to the library to borrow a book for my class.
  2. reading room
    Synonym: yàrá ìkàwé
    Òkè kelòó ni ilé-ìkàwé ilé wà? — Ó wà l'ókè kẹta.
    What floor is this house's reading room on? — It's on the third floor.

Derived terms

  • alákòóso ilé-ìkàwé ilé-ìwé (school librarian)
  • amójútó ilé-ìkàwé (librarian)
  • ẹ̀kọ́ ilé-ìkàwé (librarianship)
  • ilé-ìkàwé ẹlẹ́rọọkọ̀m̀pútà (electronic library)
  • ilé-ìkàwée mámùújáde (reference library)
  • ìmọ̀ ilé-ìkàwé (librarianship)

References

  • Awoyale, Yiwola (2008 December 19) Global Yoruba Lexical Database v. 1.0, volume LDC2008L03, Philadelphia: Linguistic Data Consortium, →DOI, →ISBN
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.