bakiteria
Yoruba

Bakitéríà
Pronunciation
- IPA(key): /bā.kī.té.ɾí.à/
Noun
bakitéríà
- bacterium
- Irú bakitéríà pọ̀ lóríṣiríṣi, àwọn kan la fi ń pọntí, àwọn kan la fi ń ṣe ajílẹ̀, ṣùgbọ́n àwọn bakitéríà kan wà tó máa ń fa àrùn, àwọn gan-an ni a ń pè ní "kòkòrò àrùn".
- There are numerous types of bacteria, some are used to brew alcohol, some are used to make compost, but there are some bacteria that cause disease, those in particular are called "pathogens".
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.