aworan
Yoruba
Alternative forms
- àòrọ́n (Èkìtì)
- اووْرَن
Etymology
From à- (“nominalizing prefix”) + wò (“to look at”) + rán (“to stare”), literally “That which is looked at intensively”
Pronunciation
- IPA(key): /à.wò.ɾã́/
Noun
àwòrán
Derived terms
- aláwòrán (“photographer”)
- ẹ̀kọ́ ìfọwọ́yàwòrán (“graphic arts”)
- ẹ̀rọ ayàwòrán (“camera”)
- àkànlò-èdè ayàwòrán (“figure of speech”)
- àwòrán alálàyé (“chart”)
- àwòrán atọ́ka (“chart”)
- àwòrán àfikereyọ́ọ̀nùyà (“pastel”)
- àwòrán àfọwọ́yà (“graphics”)
- àwòrán-atọ́ká (“diagram”)
- àwòrándìkọ (“pictogram”)
- ìyàwòrán (“drawing”)
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.